Close

“OBÌNRIN TÓÚN WÁ AHỌ́N RẸ̀ (LẸ́YÌN AMIRAH AL WASSIF)” by Akinrinade Funminiyi

Image by Gregory Akinlotan from Pixabay

OBÌNRIN TÓÚN WÁ AHỌ́N RẸ̀ (LẸ́YÌN AMIRAH AL WASSIF)
(Yoruba Language) Wọ́n sọpé ilé ìdáná làyè rẹ́ wà Níbití wọ́n ti má n gbọ́ òórùn adìye díndín Wọ́n sọpé ohùn re kọ̀gbodọ̀ jágara Àyábẹ̀ wọn ápèẹ́ lẹ́ni tó gbéraga Wọ́n tàn ọ́, wọ́n de enùrẹ níyẹ̀wù wọn Níbití wọ́n ti fi ipá bá ẹ lájọsepọ̀ Lobádi obìnrin tóún wá ahọ́n rẹ̀ Kí omádi orin tódùn sùgbọ́n tíwọn kò kọ

A WOMAN LOOKING FOR A TONGUE (AFTER READING AMIRAH AL WASSIF)

(English Translation) They said your place belongs to the kitchen Where they hear only sound of frying chicken. They said your voice shouldn’t be loud Lest they label you as being proud. They trap and tape you in their custody Where they force their ways into your body. You become a woman looking for a tongue So you won’t turn to luscious lyrics unsung.

Akinrinade Funminiyi with the pseudonym Esv_Keks is a Nigerian writer who writes from Lagos State. He has written many published and unpublished works. His works have featured in various magazines and anthologies, among which are: Writers Space Africa Monthly Magazine, Speaking Pen International Quarterly Magazine, BPPC, and Scion Magazine. He is a graduate of Estate Management department, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife, Osun State. When he’s not reading and writing, he enjoys driving, teaching, and networking with people.

scroll to top